1 Corinthians 14:21

21 aA tí kọ ọ́ nínú òfin pé,

“Nípa àwọn aláhọ́n mìíràn
àti elétè àjèjì
ní èmi ó fi ba àwọn ènìyàn yìí sọ̀rọ̀;
síbẹ̀ wọn kì yóò gbọ́ tèmi,”

ni Olúwa wí.
Copyright information for YorBMYO